-
Nọ́ńbà 9:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Bó ṣe máa ń ṣẹlẹ̀ nìyẹn: Ìkùukùu máa ń bò ó ní ọ̀sán, ohun tó rí bí iná sì máa ń bò ó ní òru.+