Jẹ́nẹ́sísì 49:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Rúbẹ́nì,+ ìwọ ni àkọ́bí+ mi, okun mi, ìbẹ̀rẹ̀ agbára ìbímọ mi, iyì àti okun rẹ ta yọ.