Jẹ́nẹ́sísì 29:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Líà wá lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Rúbẹ́nì.*+ Ó sọ pé: “Ìdí ni pé Jèhófà ti rí ìyà+ tó ń jẹ mí, ọkọ mi á wá nífẹ̀ẹ́ mi báyìí.” Ẹ́kísódù 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn olórí agbo ilé àwọn bàbá wọn nìyí: Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àkọ́bí Ísírẹ́lì+ ni Hánókù, Pálù, Hésírónì àti Kámì.+ Àwọn ni ìdílé Rúbẹ́nì. 1 Kíróníkà 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì,+ àkọ́bí Ísírẹ́lì nìyí. Òun ni àkọ́bí, àmọ́ torí pé ó kó ẹ̀gàn bá ibùsùn bàbá rẹ̀,*+ ẹ̀tọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àkọ́bí ni a fún àwọn ọmọ Jósẹ́fù+ ọmọ Ísírẹ́lì, torí náà, wọn ò kọ orúkọ rẹ̀ sínú àkọsílẹ̀ ìdílé wọn pé òun ni àkọ́bí.
32 Líà wá lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Rúbẹ́nì.*+ Ó sọ pé: “Ìdí ni pé Jèhófà ti rí ìyà+ tó ń jẹ mí, ọkọ mi á wá nífẹ̀ẹ́ mi báyìí.”
14 Àwọn olórí agbo ilé àwọn bàbá wọn nìyí: Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àkọ́bí Ísírẹ́lì+ ni Hánókù, Pálù, Hésírónì àti Kámì.+ Àwọn ni ìdílé Rúbẹ́nì.
5 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì,+ àkọ́bí Ísírẹ́lì nìyí. Òun ni àkọ́bí, àmọ́ torí pé ó kó ẹ̀gàn bá ibùsùn bàbá rẹ̀,*+ ẹ̀tọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àkọ́bí ni a fún àwọn ọmọ Jósẹ́fù+ ọmọ Ísírẹ́lì, torí náà, wọn ò kọ orúkọ rẹ̀ sínú àkọsílẹ̀ ìdílé wọn pé òun ni àkọ́bí.