-
1 Kíróníkà 9:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ṣálúmù ọmọ Kórè ọmọ Ébíásáfù ọmọ Kórà àti àwọn arákùnrin rẹ̀ láti agbo ilé bàbá rẹ̀, ìyẹn àwọn ọmọ Kórà, ló ń bójú tó iṣẹ́ náà, àwọn aṣọ́nà àgọ́, àwọn bàbá wọn ló sì ń bójú tó ibùdó Jèhófà torí àwọn ló ń ṣọ́ ọ̀nà àbáwọlé.
-