ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 25:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Nígbà tí Fíníhásì+ ọmọ Élíásárì ọmọ àlùfáà Áárónì rí i, ojú ẹsẹ̀ ló dìde láàárín àpéjọ náà, ó sì mú ọ̀kọ̀* kan dání.

  • Nọ́ńbà 31:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Mósè wá rán wọn lọ, ẹgbẹ̀rún kan (1,000) látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan láti jagun, ó ní kí Fíníhásì+ ọmọ àlùfáà Élíásárì lọ pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun náà. Ọwọ́ rẹ̀ ni àwọn ohun èlò mímọ́ àti àwọn kàkàkí+ ogun wà.

  • Jóṣúà 22:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Ni Fíníhásì ọmọ àlùfáà Élíásárì bá sọ fún àwọn àtọmọdọ́mọ Rúbẹ́nì, Gádì àti àwọn ọmọ Mánásè pé: “Lónìí, a mọ̀ pé Jèhófà wà láàárín wa, torí ẹ ò hùwà ọ̀dàlẹ̀ yìí sí Jèhófà. Ẹ ti gba àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ lọ́wọ́ Jèhófà.”

  • Àwọn Onídàájọ́ 20:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Fíníhásì+ ọmọ Élíásárì, ọmọ Áárónì, ló ń ṣiṣẹ́* níwájú rẹ̀ nígbà yẹn. Wọ́n béèrè pé: “Ṣé ká tún lọ bá àwọn arákùnrin wa, àwọn ọkùnrin Bẹ́ńjámínì jà, àbí ká má lọ mọ́?”+ Jèhófà fèsì pé: “Ẹ lọ, torí ọ̀la ni màá fi wọ́n lé yín lọ́wọ́.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́