Ẹ́kísódù 6:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Élíásárì+ ọmọ Áárónì fi ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Pútíélì ṣe aya. Ó bí Fíníhásì fún un.+ Àwọn ni olórí agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Léfì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.+ Jóṣúà 22:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Nígbà tí Fíníhásì àlùfáà, àwọn ìjòyè àpéjọ náà àti àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún* Ísírẹ́lì tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀ gbọ́ ohun tí àwọn àtọmọdọ́mọ Rúbẹ́nì, Gádì àti àwọn ọmọ Mánásè sọ, ó tẹ́ wọn lọ́rùn.+
25 Élíásárì+ ọmọ Áárónì fi ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Pútíélì ṣe aya. Ó bí Fíníhásì fún un.+ Àwọn ni olórí agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Léfì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.+
30 Nígbà tí Fíníhásì àlùfáà, àwọn ìjòyè àpéjọ náà àti àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún* Ísírẹ́lì tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀ gbọ́ ohun tí àwọn àtọmọdọ́mọ Rúbẹ́nì, Gádì àti àwọn ọmọ Mánásè sọ, ó tẹ́ wọn lọ́rùn.+