Ẹ́kísódù 31:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbàrà tó bá a sọ̀rọ̀ tán lórí Òkè Sínáì, ó fún Mósè ní wàláà Ẹ̀rí méjì,+ àwọn wàláà òkúta tí ìka Ọlọ́run+ kọ̀wé sí. Lúùkù 11:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ tó bá jẹ́ ìka Ọlọ́run + ni mo fi ń lé ẹ̀mí èṣù jáde, Ìjọba Ọlọ́run ti dé bá yín lójijì lóòótọ́.+
18 Gbàrà tó bá a sọ̀rọ̀ tán lórí Òkè Sínáì, ó fún Mósè ní wàláà Ẹ̀rí méjì,+ àwọn wàláà òkúta tí ìka Ọlọ́run+ kọ̀wé sí.
20 Àmọ́ tó bá jẹ́ ìka Ọlọ́run + ni mo fi ń lé ẹ̀mí èṣù jáde, Ìjọba Ọlọ́run ti dé bá yín lójijì lóòótọ́.+