-
Ẹ́kísódù 8:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Torí náà, àwọn àlùfáà onídán sọ fún Fáráò pé: “Ìka Ọlọ́run nìyí!”+ Àmọ́ ọkàn Fáráò ṣì le, kò sì fetí sí wọn bí Jèhófà ṣe sọ.