-
Ẹ́kísódù 8:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ni Fáráò bá sọ pé: “Màá jẹ́ kí ẹ lọ rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run yín nínú aginjù. Àmọ́, ẹ má lọ jìnnà o. Ẹ bá mi bẹ̀ ẹ́.”+
-
-
Ẹ́kísódù 9:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ẹ bẹ Jèhófà pé kí ààrá àti yìnyín látọ̀dọ̀ Ọlọ́run dáwọ́ dúró. Lẹ́yìn náà, màá jẹ́ kí ẹ lọ, mi ò sì ní dá yín dúró mọ́.”
-