Sáàmù 135:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó rán àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu sáàárín rẹ, ìwọ Íjíbítì,+Sí Fáráò àti sí gbogbo ìránṣẹ́ rẹ̀.+