-
Ẹ́kísódù 12:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Kí ẹ jẹ búrẹ́dì aláìwú láti alẹ́ ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní títí di alẹ́ ọjọ́ kọkànlélógún oṣù náà.+
-
-
Diutarónómì 16:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ṣùgbọ́n ibi tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà ni kí o ti ṣe é. Kí o fi ẹran Ìrékọjá náà rúbọ ní ìrọ̀lẹ́, gbàrà tí oòrùn bá wọ̀,+ ní déédéé àkókò tí o jáde kúrò ní Íjíbítì.
-