ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 12:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Lọ́jọ́ kẹwàá oṣù yìí, kí kálukú wọn mú àgùntàn kan+ fún ilé bàbá wọn, àgùntàn kan fún ilé kan.

  • Ẹ́kísódù 12:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Kí ẹ máa tọ́jú rẹ̀ títí di ọjọ́ kẹrìnlá oṣù yìí,+ kí gbogbo àpéjọ* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì pa á ní ìrọ̀lẹ́.*+

  • Nọ́ńbà 9:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣètò ẹbọ+ Ìrékọjá ní àkókò rẹ̀.+ 3 Ìrọ̀lẹ́* ọjọ́ kẹrìnlá oṣù yìí ni kí ẹ ṣètò rẹ̀ ní àkókò rẹ̀. Kí ẹ tẹ̀ lé gbogbo àṣẹ rẹ̀ àti ìlànà tó wà fún un tí ẹ bá ń ṣètò rẹ̀.”+

  • Mátíù 26:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Torí náà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn ṣe ohun tí Jésù sọ fún wọn gẹ́lẹ́, wọ́n sì múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá.

      20 Nígbà tó di ìrọ̀lẹ́,+ òun àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn méjìlá (12) jókòó* sídìí tábìlì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́