-
Ẹ́kísódù 3:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Màá mú kí àwọn èèyàn yìí rí ojú rere àwọn ará Íjíbítì, tí ẹ bá sì ń lọ, ó dájú pé ẹ ò ní lọ lọ́wọ́ òfo.+
-
-
Sáàmù 105:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Ó mú àwọn èèyàn rẹ̀ jáde tàwọn ti fàdákà àti wúrà;+
Ìkankan lára àwọn ẹ̀yà rẹ̀ kò sì kọsẹ̀.
-