- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 18:2-4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        2 Jẹ́tírò bàbá ìyàwó Mósè ti mú Sípórà ìyàwó Mósè sọ́dọ̀ nígbà tó ní kó pa dà sọ́dọ̀ Jẹ́tírò, 3 pẹ̀lú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ méjèèjì.+ Ọ̀kan ń jẹ́ Gẹ́ṣómù,*+ torí Mósè sọ pé, “mo ti di àjèjì nílẹ̀ òkèèrè.” 4 Èkejì ń jẹ́ Élíésérì,* torí ó sọ pé, “Ọlọ́run bàbá mi ni olùrànlọ́wọ́ mi, ẹni tó gbà mí lọ́wọ́ idà Fáráò.”+ 
 
-