Ẹ́kísódù 15:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ọ̀tá sọ pé: ‘Màá lépa wọn! Màá lé wọn bá! Màá pín ẹrù ogun wọn títí yóò fi tẹ́ mi* lọ́rùn! Màá fa idà mi yọ! Ọwọ́ mi yóò ṣẹ́gun wọn!’+
9 Ọ̀tá sọ pé: ‘Màá lépa wọn! Màá lé wọn bá! Màá pín ẹrù ogun wọn títí yóò fi tẹ́ mi* lọ́rùn! Màá fa idà mi yọ! Ọwọ́ mi yóò ṣẹ́gun wọn!’+