-
Ẹ́kísódù 14:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà tó yá, wọ́n ròyìn fún ọba Íjíbítì pé àwọn èèyàn náà ti sá lọ. Lójú ẹsẹ̀, Fáráò àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ yí ọkàn pa dà nípa àwọn èèyàn náà,+ wọ́n sì sọ pé: “Kí la ṣe yìí, kí ló dé tí a yọ̀ǹda àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n má ṣe ẹrú wa mọ́?”
-
-
Ẹ́kísódù 14:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àwọn ará Íjíbítì wá ń lépa wọn,+ gbogbo ẹṣin tó ń fa kẹ̀kẹ́ Fáráò àti àwọn agẹṣin rẹ̀ àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sì fẹ́rẹ̀ẹ́ lé wọn bá nígbà tí wọ́n pàgọ́ sẹ́gbẹ̀ẹ́ òkun, nítòsí Píháhírótì, tí wọ́n ti dojú kọ Baali-séfónì.
-