Ẹ́kísódù 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù.+ Ẹ dúró gbọn-in, kí ẹ sì rí bí Jèhófà ṣe máa gbà yín là lónìí.+ Torí àwọn ará Íjíbítì tí ẹ rí lónìí yìí, ẹ ò ní rí wọn mọ́ láé.+ Sáàmù 106:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Omi bo àwọn elénìní wọn;Kò sí ìkankan lára wọn tó yè bọ́.*+ Sáàmù 136:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó gbọn Fáráò àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú Òkun Pupa,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.
13 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù.+ Ẹ dúró gbọn-in, kí ẹ sì rí bí Jèhófà ṣe máa gbà yín là lónìí.+ Torí àwọn ará Íjíbítì tí ẹ rí lónìí yìí, ẹ ò ní rí wọn mọ́ láé.+