- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 14:27, 28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 Ni Mósè bá na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun, bí ilẹ̀ sì ṣe ń mọ́ bọ̀, òkun náà pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀. Bí àwọn ará Íjíbítì ṣe ń sá pa dà, Jèhófà bi àwọn ará Íjíbítì ṣubú sáàárín òkun.+ 28 Omi náà rọ́ pa dà, ó sì bo àwọn kẹ̀kẹ́ ogun, àwọn agẹṣin àti gbogbo ọmọ ogun Fáráò tó lépa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wọnú òkun.+ Kò sí ìkankan nínú wọn tó yè é.+ 
 
-