Ẹ́kísódù 15:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Míríámù fi orin dá àwọn ọkùnrin lóhùn pé: “Ẹ kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+ Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.”+ Sáàmù 136:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó gbọn Fáráò àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú Òkun Pupa,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.
21 Míríámù fi orin dá àwọn ọkùnrin lóhùn pé: “Ẹ kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+ Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.”+