-
Nọ́ńbà 33:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Wọ́n wá kúrò ní Élímù, wọ́n sì pàgọ́ sẹ́gbẹ̀ẹ́ Òkun Pupa. 11 Lẹ́yìn náà, wọ́n kúrò ní Òkun Pupa, wọ́n sì pàgọ́ sí aginjù Sínì.+
-