-
Ẹ́kísódù 16:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Lẹ́yìn tí wọ́n kúrò ní Élímù, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dé aginjù Sínì,+ tó wà láàárín Élímù àti Sínáì. Wọ́n dé ibẹ̀ ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kejì tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.
-