ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 1:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Wọ́n wá yan àwọn ọ̀gá* lé wọn lórí láti máa fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.+ Wọ́n sì kọ́ àwọn ìlú tí wọ́n ń kó nǹkan pa mọ́ sí fún Fáráò. Orúkọ àwọn ìlú náà ni Pítómù àti Rámísésì.+

  • Àìsáyà 63:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Nínú gbogbo ìdààmú wọn, ìdààmú bá òun náà.+

      Ìránṣẹ́ òun fúnra rẹ̀* sì gbà wọ́n là.+

      Ó tún wọn rà nínú ìfẹ́ rẹ̀ àti ìyọ́nú rẹ̀,+

      Ó gbé wọn sókè, ó sì rù wọ́n ní gbogbo ìgbà àtijọ́.+

  • Ìṣe 7:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Mo ti rí bí wọ́n ṣe ń fìyà jẹ àwọn èèyàn mi tó wà ní Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ bí wọ́n ṣe ń kérora,+ mo ti sọ̀ kalẹ̀ wá láti gbà wọ́n sílẹ̀. Ní báyìí, wá, màá rán ọ lọ sí Íjíbítì.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́