-
Ẹ́kísódù 22:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 “Tí ẹnì kan bá dá iná, tó wá ràn mọ́ àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún, tó sì jó àwọn ìtí ọkà, tó jó ọkà tó wà ní ìdúró tàbí oko run, ẹni tó dá iná náà gbọ́dọ̀ san nǹkan kan láti fi dípò ohun tó jóná.
-
-
Ẹ́kísódù 22:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Àmọ́ tí ẹnikẹ́ni bá yá ẹran lọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ̀, tí ẹran náà wá di aláàbọ̀ ara tàbí tó kú nígbà tí ẹni tó ni ín kò sí níbẹ̀, ẹni tó yá a yóò san nǹkan kan dípò rẹ̀.
-