Sáàmù 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wàá dá ẹjọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba àti ẹni tí a ni lára,+Kí ẹni kíkú lásánlàsàn* má bàa dẹ́rù bà wọ́n mọ́.+ Jémíìsì 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+
18 Wàá dá ẹjọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba àti ẹni tí a ni lára,+Kí ẹni kíkú lásánlàsàn* má bàa dẹ́rù bà wọ́n mọ́.+
4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+