Àìsáyà 51:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Èmi fúnra mi ni Ẹni tó ń tù yín nínú.+ Ṣé ó wá yẹ kí ẹ máa bẹ̀rù ẹni kíkú tó máa kú+Àti ọmọ aráyé tó máa rọ bíi koríko tútù?
12 “Èmi fúnra mi ni Ẹni tó ń tù yín nínú.+ Ṣé ó wá yẹ kí ẹ máa bẹ̀rù ẹni kíkú tó máa kú+Àti ọmọ aráyé tó máa rọ bíi koríko tútù?