Òwe 25:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Tí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ,* fún un ní oúnjẹ jẹ;Tí òùngbẹ bá sì ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mu,+ 1 Tẹsalóníkà 5:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ rí i pé ẹnikẹ́ni ò fi búburú san búburú fún ẹnì kankan,+ kí ẹ sì máa fìgbà gbogbo wá ohun rere fún ara yín àti fún gbogbo àwọn míì.+
21 Tí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ,* fún un ní oúnjẹ jẹ;Tí òùngbẹ bá sì ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mu,+ 1 Tẹsalóníkà 5:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ rí i pé ẹnikẹ́ni ò fi búburú san búburú fún ẹnì kankan,+ kí ẹ sì máa fìgbà gbogbo wá ohun rere fún ara yín àti fún gbogbo àwọn míì.+
15 Ẹ rí i pé ẹnikẹ́ni ò fi búburú san búburú fún ẹnì kankan,+ kí ẹ sì máa fìgbà gbogbo wá ohun rere fún ara yín àti fún gbogbo àwọn míì.+