ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 12:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Kí ẹ wó àwọn pẹpẹ wọn, kí ẹ fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn túútúú,+ kí ẹ dáná sun àwọn òpó òrìṣà* wọn, kí ẹ sì gé ère àwọn ọlọ́run wọn+ tí wọ́n gbẹ́ lulẹ̀, kí orúkọ wọn lè pa rẹ́ kúrò níbẹ̀.+

  • Jóṣúà 23:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Torí náà, ẹ jẹ́ onígboyà gidigidi kí ẹ lè máa pa gbogbo ohun tí a kọ sínú ìwé Òfin+ Mósè mọ́, kí ẹ sì máa tẹ̀ lé e, kí ẹ má ṣe yà kúrò nínú rẹ̀ sí ọ̀tún tàbí sí òsì,+ 7 ẹ má ṣe bá àwọn orílẹ̀-èdè tó ṣẹ́ kù pẹ̀lú yín yìí ṣe wọlé-wọ̀de.+ Ẹ ò tiẹ̀ gbọ́dọ̀ dárúkọ àwọn ọlọ́run wọn,+ ẹ ò gbọ́dọ̀ fi wọ́n búra, ẹ ò gbọ́dọ̀ sìn wọ́n láé, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́