Ẹ́kísódù 23:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Kí ẹ rí i pé ẹ ṣe gbogbo ohun tí mo sọ fún yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ dárúkọ àwọn ọlọ́run míì; kò gbọ́dọ̀ ti ẹnu* yín jáde.+ Jóṣúà 23:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 ẹ má ṣe bá àwọn orílẹ̀-èdè tó ṣẹ́ kù pẹ̀lú yín yìí ṣe wọlé-wọ̀de.+ Ẹ ò tiẹ̀ gbọ́dọ̀ dárúkọ àwọn ọlọ́run wọn,+ ẹ ò gbọ́dọ̀ fi wọ́n búra, ẹ ò gbọ́dọ̀ sìn wọ́n láé, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún wọn.+
13 “Kí ẹ rí i pé ẹ ṣe gbogbo ohun tí mo sọ fún yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ dárúkọ àwọn ọlọ́run míì; kò gbọ́dọ̀ ti ẹnu* yín jáde.+
7 ẹ má ṣe bá àwọn orílẹ̀-èdè tó ṣẹ́ kù pẹ̀lú yín yìí ṣe wọlé-wọ̀de.+ Ẹ ò tiẹ̀ gbọ́dọ̀ dárúkọ àwọn ọlọ́run wọn,+ ẹ ò gbọ́dọ̀ fi wọ́n búra, ẹ ò gbọ́dọ̀ sìn wọ́n láé, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún wọn.+