Nọ́ńbà 20:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, a ké pe Jèhófà,+ ó gbọ́ wa, ó sì rán áńgẹ́lì+ kan láti mú wa kúrò ní Íjíbítì, a ti wá dé Kádéṣì báyìí, ìlú tó wà ní ààlà ilẹ̀ rẹ.
16 Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, a ké pe Jèhófà,+ ó gbọ́ wa, ó sì rán áńgẹ́lì+ kan láti mú wa kúrò ní Íjíbítì, a ti wá dé Kádéṣì báyìí, ìlú tó wà ní ààlà ilẹ̀ rẹ.