Ẹ́kísódù 20:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn èèyàn náà ò kúrò ní ọ̀ọ́kán níbi tí wọ́n dúró sí, àmọ́ Mósè sún mọ́ ìkùukùu* tó ṣú dùdù náà níbi tí Ọlọ́run tòótọ́ wà.+ Nọ́ńbà 12:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ojúkojú* ni mò ń bá a sọ̀rọ̀,+ láì fọ̀rọ̀ pa mọ́, kì í ṣe lówelówe; ìrísí Jèhófà ló sì ń rí. Kí wá nìdí tí ẹ̀rù ò fi bà yín láti sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí Mósè ìránṣẹ́ mi?”
21 Àwọn èèyàn náà ò kúrò ní ọ̀ọ́kán níbi tí wọ́n dúró sí, àmọ́ Mósè sún mọ́ ìkùukùu* tó ṣú dùdù náà níbi tí Ọlọ́run tòótọ́ wà.+
8 Ojúkojú* ni mò ń bá a sọ̀rọ̀,+ láì fọ̀rọ̀ pa mọ́, kì í ṣe lówelówe; ìrísí Jèhófà ló sì ń rí. Kí wá nìdí tí ẹ̀rù ò fi bà yín láti sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí Mósè ìránṣẹ́ mi?”