Ẹ́kísódù 33:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ojúkojú,+ bí ìgbà téèyàn méjì ń bá ara wọn sọ̀rọ̀. Nígbà tó pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn náà, Jóṣúà+ ọmọ Núnì, òjíṣẹ́ rẹ̀ àti ìránṣẹ́ rẹ̀+ ò kúrò níbi àgọ́ náà. Diutarónómì 34:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ látìgbà náà, kò tíì sí wòlíì kankan ní Ísírẹ́lì bíi Mósè,+ ẹni tí Jèhófà mọ̀ lójúkojú.+
11 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ojúkojú,+ bí ìgbà téèyàn méjì ń bá ara wọn sọ̀rọ̀. Nígbà tó pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn náà, Jóṣúà+ ọmọ Núnì, òjíṣẹ́ rẹ̀ àti ìránṣẹ́ rẹ̀+ ò kúrò níbi àgọ́ náà.