-
1 Àwọn Ọba 8:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Torí náà, ìyẹ́ apá àwọn kérúbù náà nà jáde sórí ibi tí Àpótí náà wà, tó fi jẹ́ pé àwọn kérúbù náà ṣíji bo Àpótí náà àti àwọn ọ̀pá rẹ̀.+
-