ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 37:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Lẹ́yìn náà, ó fi ògidì wúrà ṣe àwọn ohun èlò tó wà lórí tábìlì—àwọn abọ́ ìjẹun rẹ̀, àwọn ife rẹ̀, àwọn abọ́ rẹ̀ àti àwọn ṣágo tí wọ́n á máa da ọrẹ ohun mímu látinú rẹ̀.+

  • Nọ́ńbà 4:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “Kí wọ́n tún na aṣọ aláwọ̀ búlúù bo tábìlì búrẹ́dì àfihàn,+ kí wọ́n sì kó àwọn àwo ìjẹun sórí rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ife, àwọn abọ́ àti àwọn ṣágo ọrẹ ohun mímu;+ kí búrẹ́dì+ ọrẹ máa wà lórí rẹ̀ nígbà gbogbo.

  • 1 Àwọn Ọba 7:48
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Sólómọ́nì ṣe gbogbo nǹkan èlò ilé Jèhófà, àwọn ni: pẹpẹ+ wúrà; tábìlì wúrà+ tí wọ́n á máa kó búrẹ́dì àfihàn sí;

  • 1 Àwọn Ọba 7:50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 àwọn bàsíà, àwọn ohun tí wọ́n fi ń pa fìtílà,+ àwọn abọ́, àwọn ife+ àti àwọn ìkóná+ tí á fi ògidì wúrà ṣe; ihò àwọn ilẹ̀kùn ilé inú lọ́hùn-ún,+ ìyẹn, Ibi Mímọ́ Jù Lọ àti ihò àwọn ilẹ̀kùn ilé tẹ́ńpìlì+ tí a fi wúrà ṣe.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́