40 àwọn aṣọ ìdábùú tí wọ́n máa ta sí àgbàlá náà, àwọn òpó rẹ̀ àti àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò rẹ̀,+ aṣọ tí wọ́n máa ta+ sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá, àwọn okùn àgọ́ rẹ̀ àti àwọn èèkàn àgọ́ rẹ̀+ àti gbogbo ohun èlò tí wọ́n máa fi ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìjọsìn náà, ní àgọ́ ìpàdé;