ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 2:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Àmọ́ lọ́jọ́ kejì, ó jáde, ó sì rí àwọn ọkùnrin Hébérù méjì tó ń bára wọn jà. Ó wá sọ fún ẹni tó jẹ̀bi pé: “Kí ló dé tí o lu ọ̀rẹ́ rẹ?”+ 14 Nìyẹn bá fèsì pé: “Ta ló fi ọ́ ṣe olórí àti onídàájọ́ wa? Ṣé o fẹ́ pa mí bí o ṣe pa ọmọ Íjíbítì yẹn ni?”+ Ẹ̀rù wá ba Mósè, ó sì sọ pé: “Ó dájú pé àwọn èèyàn ti mọ̀ nípa ọ̀rọ̀ yìí!”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́