Nọ́ńbà 18:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àwọn ọmọ Léfì fúnra wọn ni kó máa ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé, àwọn sì ni kó máa dáhùn fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Àṣẹ tó máa wà títí lọ jálẹ̀ gbogbo ìran yín ni pé wọn ò gbọ́dọ̀ ní ogún láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
23 Àwọn ọmọ Léfì fúnra wọn ni kó máa ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé, àwọn sì ni kó máa dáhùn fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Àṣẹ tó máa wà títí lọ jálẹ̀ gbogbo ìran yín ni pé wọn ò gbọ́dọ̀ ní ogún láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+