Ẹ́kísódù 39:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó fi wúrà, fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀* lílọ́ tó dáa ṣe éfódì.+
2 Ó fi wúrà, fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀* lílọ́ tó dáa ṣe éfódì.+