ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 1:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Kó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé orí ẹran náà, ọrẹ rẹ̀ yóò sì ní ìtẹ́wọ́gbà, á sì jẹ́ ètùtù fún un.

  • Léfítíkù 8:18-21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ó mú àgbò tó fẹ́ fi rú ẹbọ sísun náà wá sí tòsí, Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì gbé ọwọ́ lé orí àgbò náà.+ 19 Lẹ́yìn náà, Mósè pa á, ó sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sí gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ. 20 Ó gé àgbò náà sí wẹ́wẹ́, Mósè sì mú kí orí àgbò náà, àwọn ègé rẹ̀ àti ọ̀rá rẹ̀ líle* rú èéfín. 21 Ó fi omi fọ ìfun àti ẹsẹ̀ rẹ̀, Mósè sì mú kí odindi àgbò náà rú èéfín lórí pẹpẹ. Ẹbọ sísun tó ní òórùn dídùn* ni. Ọrẹ àfinásun sí Jèhófà ló jẹ́, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́