Léfítíkù 8:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Mósè tún mú igẹ̀, ó sì fì í síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì níwájú Jèhófà.+ Ó di ìpín Mósè látinú àgbò àfiyanni, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.+ Sáàmù 99:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mósè àti Áárónì wà lára àwọn àlùfáà rẹ̀,+Sámúẹ́lì sì wà lára àwọn tó ń ké pe orúkọ rẹ̀.+ Wọ́n ń pe Jèhófà,Ó sì ń dá wọn lóhùn.+
29 Mósè tún mú igẹ̀, ó sì fì í síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì níwájú Jèhófà.+ Ó di ìpín Mósè látinú àgbò àfiyanni, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.+
6 Mósè àti Áárónì wà lára àwọn àlùfáà rẹ̀,+Sámúẹ́lì sì wà lára àwọn tó ń ké pe orúkọ rẹ̀.+ Wọ́n ń pe Jèhófà,Ó sì ń dá wọn lóhùn.+