-
Léfítíkù 7:34, 35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Torí mo mú igẹ̀ ọrẹ fífì àti ẹsẹ̀ ìpín mímọ́ náà látinú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, mo sì fún àlùfáà Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kó jẹ́ ìlànà tó máa wà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ títí lọ.
35 “‘Ìpín tí wọ́n yà sọ́tọ̀ fún àwọn àlùfáà nìyí, fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, látinú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, ní ọjọ́ tó mú wọn wá síwájú Jèhófà láti ṣe àlùfáà rẹ̀.+
-