Léfítíkù 22:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “‘Ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí* ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́.+ Àlejò èyíkéyìí tó wà lọ́dọ̀ àlùfáà tàbí alágbàṣe ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́. Nọ́ńbà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+
10 “‘Ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí* ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́.+ Àlejò èyíkéyìí tó wà lọ́dọ̀ àlùfáà tàbí alágbàṣe ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́.
10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+