2 Kíróníkà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Síwájú sí i, ó ṣe bàsíà mẹ́wàá fún fífọ nǹkan, ó gbé márùn-ún sí apá ọ̀tún àti márùn-ún sí apá òsì.+ Inú wọn ni wọ́n ti ń ṣan àwọn ohun tí wọ́n ń lò fún ẹbọ sísun.+ Àmọ́ Òkun náà jẹ́ ti àwọn àlùfáà láti máa fi wẹ apá àti ẹsẹ̀ wọn.+
6 Síwájú sí i, ó ṣe bàsíà mẹ́wàá fún fífọ nǹkan, ó gbé márùn-ún sí apá ọ̀tún àti márùn-ún sí apá òsì.+ Inú wọn ni wọ́n ti ń ṣan àwọn ohun tí wọ́n ń lò fún ẹbọ sísun.+ Àmọ́ Òkun náà jẹ́ ti àwọn àlùfáà láti máa fi wẹ apá àti ẹsẹ̀ wọn.+