-
Ẹ́kísódù 30:31, 32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “Kí o sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Òróró yìí ni yóò máa jẹ́ òróró àfiyanni mímọ́ fún mi ní ìrandíran yín.+ 32 Èèyàn kankan ò gbọ́dọ̀ fi pa ara, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe ohunkóhun tó ní irú èròjà rẹ̀. Ohun mímọ́ ni. Yóò máa jẹ́ ohun mímọ́ fún yín.
-