Ẹ́kísódù 37:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó tún ṣe òróró àfiyanni mímọ́+ àti ògidì tùràrí onílọ́fínńdà,+ ó ro àwọn èròjà rẹ̀ pọ̀ dáadáa.* Sáàmù 141:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí àdúrà mi dà bíi tùràrí+ tí a ṣètò sílẹ̀ níwájú rẹ,+Kí ọwọ́ tí mo gbé sókè dà bí ọrẹ ọkà ìrọ̀lẹ́.+ Ìfihàn 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà tó gbà á, àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin àti àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún + (24) náà wólẹ̀ níwájú Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní háàpù kan lọ́wọ́ àti abọ́ wúrà tí tùràrí kún inú rẹ̀. (Tùràrí náà túmọ̀ sí àdúrà àwọn ẹni mímọ́.)+
2 Kí àdúrà mi dà bíi tùràrí+ tí a ṣètò sílẹ̀ níwájú rẹ,+Kí ọwọ́ tí mo gbé sókè dà bí ọrẹ ọkà ìrọ̀lẹ́.+
8 Nígbà tó gbà á, àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin àti àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún + (24) náà wólẹ̀ níwájú Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní háàpù kan lọ́wọ́ àti abọ́ wúrà tí tùràrí kún inú rẹ̀. (Tùràrí náà túmọ̀ sí àdúrà àwọn ẹni mímọ́.)+