Ẹ́kísódù 37:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó tún ṣe òróró àfiyanni mímọ́+ àti ògidì tùràrí onílọ́fínńdà,+ ó ro àwọn èròjà rẹ̀ pọ̀ dáadáa.* 1 Àwọn Ọba 1:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ni àlùfáà Sádókù bá mú ìwo òróró+ láti inú àgọ́,+ ó sì fòróró yan Sólómọ́nì,+ wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í fun ìwo, gbogbo èèyàn náà sì ń kígbe pé: “Kí ẹ̀mí Ọba Sólómọ́nì gùn o!” Sáàmù 89:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Mo ti rí Dáfídì ìránṣẹ́ mi;+Mo ti fi òróró mímọ́ mi yàn án.+
39 Ni àlùfáà Sádókù bá mú ìwo òróró+ láti inú àgọ́,+ ó sì fòróró yan Sólómọ́nì,+ wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í fun ìwo, gbogbo èèyàn náà sì ń kígbe pé: “Kí ẹ̀mí Ọba Sólómọ́nì gùn o!”