ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 9:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Nígbà náà, mo rí i pé ẹ ti ṣẹ Jèhófà Ọlọ́run yín! Ẹ ti ṣe ọmọ màlúù onírin* fún ara yín. Ẹ ti yára kúrò ní ọ̀nà tí Jèhófà pa láṣẹ pé kí ẹ máa rìn.+

  • Àìsáyà 46:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Àwọn kan wà tó ń kó wúrà jáde yàlàyòlò látinú àpò wọn;

      Wọ́n ń wọn fàdákà lórí òṣùwọ̀n.

      Wọ́n gba oníṣẹ́ irin síṣẹ́, ó sì fi ṣe ọlọ́run.+

      Wọ́n wá wólẹ̀, àní, wọ́n jọ́sìn rẹ̀.*+

  • Ìṣe 7:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 Nítorí náà, wọ́n ṣe ère ọmọ màlúù kan lákòókò yẹn, wọ́n mú ẹbọ wá fún ère náà, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbádùn ara wọn nítorí àwọn iṣẹ́ ọwọ́ wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́