ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 15:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Àwọn èèyàn náà wá ń kùn sí Mósè+ pé: “Kí la máa mu báyìí?”

  • Ẹ́kísódù 16:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì bẹ̀rẹ̀ sí í kùn sí Mósè àti Áárónì ní aginjù.+

  • Ẹ́kísódù 17:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Àwọn èèyàn náà wá bẹ̀rẹ̀ sí í bá Mósè jà,+ wọ́n sì ń sọ pé: “Fún wa lómi mu.” Àmọ́ Mósè bi wọ́n pé: “Kí ló dé tí ẹ̀ ń bá mi jà? Kí ló dé tí ẹ̀ ń dán Jèhófà wò?”+

  • Diutarónómì 9:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “Rántí, má sì gbàgbé bí o ṣe múnú bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ní aginjù.+ Láti ọjọ́ tí ẹ ti kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì títí ẹ fi dé ibí yìí lẹ ti ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà.+

  • Diutarónómì 31:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́!

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́