Ẹ́kísódù 32:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: “Mo ti rí i pé alágídí* ni àwọn èèyàn yìí.+ Sáàmù 78:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọn ò ní dà bí àwọn baba ńlá wọn,Ìran alágídí àti ọlọ̀tẹ̀,+Ìran tí ọkàn wọn ń ṣe ségesège*+Tí ẹ̀mí wọn ò sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run.
8 Wọn ò ní dà bí àwọn baba ńlá wọn,Ìran alágídí àti ọlọ̀tẹ̀,+Ìran tí ọkàn wọn ń ṣe ségesège*+Tí ẹ̀mí wọn ò sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run.