Ẹ́kísódù 23:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+ Ẹ́kísódù 33:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín,+ màá sì lé àwọn ọmọ Kénáánì kúrò, pẹ̀lú àwọn Ámórì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+
20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+
2 Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín,+ màá sì lé àwọn ọmọ Kénáánì kúrò, pẹ̀lú àwọn Ámórì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+