Ẹ́kísódù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* ń bímọ, wọ́n sì ń pọ̀ sí i, wọ́n ń bí sí i, wọ́n sì túbọ̀ ń lágbára gidigidi, débi pé wọ́n kún ilẹ̀ náà.+ Sáàmù 105:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọlọ́run mú kí àwọn èèyàn rẹ̀ pọ̀ rẹpẹtẹ;+Ó mú kí wọ́n lágbára ju àwọn ọ̀tá wọn lọ,+ 25 Àwọn tó jẹ́ kí ọkàn wọn yí pa dà kí wọ́n lè kórìíra àwọn èèyàn rẹ̀,Kí wọ́n sì dìtẹ̀ mọ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.+
7 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* ń bímọ, wọ́n sì ń pọ̀ sí i, wọ́n ń bí sí i, wọ́n sì túbọ̀ ń lágbára gidigidi, débi pé wọ́n kún ilẹ̀ náà.+
24 Ọlọ́run mú kí àwọn èèyàn rẹ̀ pọ̀ rẹpẹtẹ;+Ó mú kí wọ́n lágbára ju àwọn ọ̀tá wọn lọ,+ 25 Àwọn tó jẹ́ kí ọkàn wọn yí pa dà kí wọ́n lè kórìíra àwọn èèyàn rẹ̀,Kí wọ́n sì dìtẹ̀ mọ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.+